NEWS| MIXTAPE | FREEBEAT | ALBUM |


 

« | »

Olufemicrown – Loruko Jesu

Posted by on May 9th, 2020

Shortenlink and get Paid

Song Lyrics

Chorus: 2xLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooAadara fun Ooo —  Aadara fun OooAadara funmiiii
Verse 1Loruko Jesu mosure fun ooo, Ojo aayo re aade, Ibanuje koni je tire, Ire ayo yio too waa, Idunnu igbala yio je tire,Aaa laanu re oo ni ku, Oogo ree yio bu yo, Ibukun oluwa yio je tire, Loruko Jesu mo gba adura fun oo pe adara fun ooo.


Chorus: 2xLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooAadara fun Ooo —  Aadara fun OooAadara funmiiii.


Verse 2. Loruko Jesu waa bori ota, Ekun ose koni je tire, aai rina aai rilo koni je tire, Igbega lenu ise lenu owo ree, Olugdala yio jaa fun oo, Ase yori lori idawole re, Ooogoo ree yio tan Kaye, Ogun otaa koni bori re, Loruko Jesu moo sure fun oo pe adara fun oo.


Chorus: 2xLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooAadara fun Ooo —  Aadara fun OooAadara funmiiii
Verse 3. Loruko Jesu ona re aala, Loruko Jesu wa rin na kore, Loruko Jesu afoya ibi, Loruko Jesu aye yee ee, Poruko Asian ba fo loo, Poruko Jesu eru sa wole, Poruko Jesu ota sa wogbo, Loruko Jesu no sami ase pe adara fun oo.


Chorus: 4x Loruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooLoruko Jesu Ooo — Loruko Jesu oooAadara fun Ooo —  Aadara fun OooAadara funmiiii

DOWNLOAD MP3 NOW


.